🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ All languages
See More Jesus

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìmọ̀? — Apá 2 · Àwọn Ẹsẹ Bíbélì KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.

This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.

Òwe 18:15 — Ọkàn olóye ní i gba ìmọ̀; etí ________ ní í ṣe àwárí rẹ̀.
ọlọ́gbọ́n
sọ̀rọ̀
ẹlẹ́ṣẹ̀
Òwe 2:3 — àní, bí ìwọ bá ké tọ ìmọ̀ lẹ́yìn, tí ìwọ sì gbé ________ rẹ sókè fún òye
ọ̀tá
ohùn
ìdílé
Òwe 2:5 — Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀rù Olúwa, ìwọ yóò sì rí ________ Ọlọ́run.
òye
kórìíra
ìmọ̀
Òwe 19:2 — Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀, tàbí kí ènìyàn kánjú kí ó sì ________.
fetísílẹ̀
ṣìnà
adé
Johanu 17:3 — Ìyè ________ náà sì ni èyí, kí wọn kí ó lè mọ ìwọ nìkan Ọlọ́run òtítọ́, àti Jesu Kristi, ẹni tí ìwọ rán.
afọ́jú
àìnípẹ̀kun
ìsinsin
Filipi 3:8 — Nítòótọ́ láìṣe àní àní mo sì ka ohun gbogbo sí òfo nítorí ìtayọ ìmọ̀ Kristi Jesu Olúwa mi; nítorí ẹni ti mo ti ṣòfò ohun gbogbo, mo si kà wọn sí ohun tí kò ní èrè, kí èmi lè ________ Kristi
aláìlábàwọ́n
jèrè
gbin
2 Kọrinti 4:6 — Nítorí Ọlọ́run ni ẹni tí ó wí pé, “Kí ìmọ́lẹ̀ ó tan láti inú ________ jáde,” òun ní ó ti ń tan mọ́lẹ̀ lọ́kàn wa, láti fún wa ní ìmọ́lẹ̀ ìmọ̀ ògo Ọlọ́run ní ojú Jesu Kristi.
ọgbọ́n
ìgbèkùn
òkùnkùn
Romu 1:28 — Àti gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti kọ̀ láti gba Ọlọ́run nínú ________ tí ó tọ́, Ọlọ́run fi wọ́n fún iyè ríra láti ṣe ohun tí kò tọ́ fún wọn láti ṣe.
ọrọ̀
nìkan
ìmọ̀
1 Kọrinti 8:1 — Ní ìsinsin yìí, nípa tí oúnjẹ ti a fi rú ẹbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé gbogbo wa ni a ní ìmọ̀. Imọ̀ a máa fẹ́ mu ní gbéraga, ṣùgbọ́n ________ ní gbé ni ró.
ìwà
ẹ̀rí
ìfẹ́
2 Timotiu 3:7 — Wọ́n ń fi ìgbà gbogbo kẹ́kọ̀ọ́, wọ́n kò sì lè dé ojú ________ òtítọ́.
asán
ìmọ̀
nìkan
1 Timotiu 6:20 — ________, máa ṣọ ohun tí a fi sí ìkáwọ́ rẹ, yà kúrò nínú ọ̀rọ̀ asán àti ìjiyàn ohun tí a ń fi èké pè ni ìmọ̀;
Timotiu
Makedonia
Kesari
Isaiah 11:9 — Wọn kò ní ṣe ni léṣe tàbí pa ni run ní gbogbo ________ mímọ́ mi, nítorí gbogbo ayé yóò kún fún ìmọ̀ Olúwa gẹ́gẹ́ bí omi ti bo Òkun.
odò
òkè
òtítọ́
Habakuku 2:14 — Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ________ Olúwa, bí omi ti bo Òkun.
ìbínú
ohùn
ògo
Numeri 14:21 — Ṣùgbọ́n nítòótọ́ bí mo ti wà ________, gbogbo ayé yóò kún fún ògo Olúwa.
sọkún
láààyè
ìgbọ̀nwọ́
Hosea 6:3 — Ẹ jẹ́ kí a mọ Olúwa; ẹ jẹ́ kí a tẹ̀síwájú láti mọ̀ ọ́n. Gẹ́gẹ́ bí ________ ṣe ń yọ, yóò jáde; yóò tọ̀ wá wá bí òjò, bí òjò àkọ́rọ̀ ti ń bomirin ilẹ̀.”
ọlọ́gbọ́n
oòrùn
ìbùkún
2 Peteru 3:18 — Ṣùgbọ́n ẹ máa dàgbà nínú ________ àti nínú ìmọ̀ Olúwa àti Olùgbàlà wa Jesu Kristi. Ẹni tí ògo wà fún nísinsin yìí àti títí láé! Àmín.
asán
ọlá
oore-ọ̀fẹ́

← Back to the study