Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọgbọ́n? — Ìpìlẹ̀ Náà · Àwọn Ìwé Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
Isaiah 11:2 — Ẹ̀mí Olúwa yóò sì bà lé e, ẹ̀mí ọgbọ́n àti ti òye, ẹ̀mí ________ àti ti agbára, ẹ̀mí ìmọ̀ àti ti ìbẹ̀rù Olúwa.
ìmọ̀ràn
ọ̀dọ́-àgùntàn
níhìn-ín
Isaiah 11:3 — Òun yóò sì ní inú dídùn nínú ìbẹ̀rù Olúwa. Òun kì yóò ṣe ________ pẹ̀lú ohun tí ó fi ojú u rẹ̀ rí, tàbí pẹ̀lú ohun tí ó fi etí i rẹ̀ gbọ́
run
ìdájọ́
dúró
Òwe 2:6 — Nítorí Olúwa ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n, láti ________ rẹ̀ sì ni ìmọ̀ àti òye ti ń wá.
ẹnu
ọkàn
agbára
Òwe 2:7 — Ó to ìgbàlà fún àwọn olódodo, Òun ni ________ fún àwọn tí ń rìn déédé
àgàbàgebè
ègún
asà
Òwe 2:4 — bí ìwọ bá ṣàfẹ́rí rẹ̀ bí i ________ tí ìwọ sì wa kiri bí ìṣúra tí a fi pamọ́.
fàdákà
dídùn
yọ̀
Òwe 2:5 — Nígbà náà ni ìwọ yóò bẹ̀rù Olúwa, ìwọ yóò sì rí ________ Ọlọ́run.
òye
kórìíra
ìmọ̀
Saamu 103:11 — Nítorí bí ________ ṣe ga sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ rẹ̀ tóbi sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀.
òfin
ọ̀run
ẹ̀ṣẹ̀
Òwe 8:13 — Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìkórìíra ibi mo kórìíra ________ àti agídí, ìwà ibi àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.
ibùsùn
àlejò
ìgbéraga
Òwe 16:6 — Nípasẹ̀ ìfẹ́ àti òtítọ́ a ṣe ètùtù ________ nípasẹ̀ ìbẹ̀rù Olúwa ènìyàn sá fún ibi.
ẹ̀ṣẹ̀
kọ́
kórìíra
Òwe 19:23 — Ìbẹ̀rù Olúwa ń mú ________ wá; nígbà náà ọkàn ń balẹ̀, láìsí ewu.
sílẹ̀
aláìní
ìyè
Matiu 10:28 — Ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn tí ó le pa ara ________; ṣùgbọ́n tí wọn kò lè pa ẹ̀mí. Ẹ bẹ̀rù Ẹni tí ó le pa ẹ̀mí àti ara run ní ọ̀run àpáàdì.
nìkan
Èéṣe
ìmọ́lẹ̀
Ìṣe àwọn Aposteli 9:31 — Nígbà náà ni ìjọ wà ni àlàáfíà yíká gbogbo Judea àti ni Galili àti ni Samaria, wọn ń fẹsẹ̀múlẹ̀, wọn ń rìn ní ìbẹ̀rù Olúwa, àti ni ________ Ẹ̀mí Mímọ́, wọn ń pọ̀ sí i.
bẹ̀bẹ̀
ìyànjú
ìtùnú
2 Kọrinti 7:1 — Nítorí náà, ẹ̀yin olùfẹ́, bí a ti ní àwọn ìlérí wọ̀nyí, ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wá mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí, kí a sọ ìwà mímọ́ dí ________ nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
pípé
sùúrù
ìgbọ́ràn
Filipi 2:12 — Nítorí náà ẹ̀yin ará mi, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin ti ń gbọ́rọ̀ nígbà gbogbo, kì í ṣe nígbà ti mo wà lọ́dọ̀ yín nìkan, ṣùgbọ́n pàápàá nísinsin yìí tí èmi kò sí ni àárín yín, ẹ máa ṣiṣẹ́ ________ yín yọrí pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ìwárìrì
ìgbàlà
ìwà
asán
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
