Kín Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìmọ̀? — Ìpìlẹ̀ Náà · Àwọn Ẹsẹ Bíbélì KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
Òwe 10:14 — Ọlọ́gbọ́n ènìyàn kó ìmọ̀ jọ, ṣùgbọ́n ẹnu aláìgbọ́n a máa ṣokùnfà ________.
ìparun
ayọ̀
iṣẹ́
Òwe 11:9 — Aláìmọ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba ________ rẹ̀ jẹ́, ṣùgbọ́n nípasẹ̀ ìmọ̀ olódodo sá àsálà.
ahọ́n
ọ̀rẹ́
aládùúgbò
Òwe 12:1 — Ẹnikẹ́ni tí ó fẹ́ ẹ̀kọ́ fẹ́ ìmọ̀, ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó kórìíra ________ jẹ́ aláìgbọ́n.
ipa
ìbáwí
ọ̀rẹ́
Òwe 15:14 — Ọkàn olóye ń wá ìmọ̀ ṣùgbọ́n ẹnu aláìgbọ́n ń fẹ́ ìwà ________ bí ẹní jẹun.
ẹ̀kọ́
etí
òmùgọ̀
Òwe 18:15 — Ọkàn olóye ní i gba ìmọ̀; etí ________ ní í ṣe àwárí rẹ̀.
ọlọ́gbọ́n
sọ̀rọ̀
ẹlẹ́ṣẹ̀
Òwe 24:5 — ________ ènìyàn ní agbára púpọ̀, ènìyàn tí ó ní ìmọ̀ sì ń ní agbára sí i.
Ọlọ́gbọ́n
sọ̀rọ̀
òǹgbẹ
Isaiah 5:13 — Nítorí náà àwọn ènìyàn mi yóò lọ sí ________ nítorí òye kò sí fún wọn, ebi ni yóò pa àwọn ọlọ́lá wọn kú; ẹgbàágbèje wọn ni òǹgbẹ yóò sì gbẹ.
ọgbọ́n
ìwà
ìgbèkùn
Luku 4:18 — “Ẹ̀mí Olúwa ń bẹ lára mi, nítorí tí ó fi àmì òróró yàn mí láti wàásù ìyìnrere fún àwọn òtòṣì. Ó ti rán mi wá láti wàásù ìdásílẹ̀ fún àwọn ________, àti ìmúnríran fún àwọn afọ́jú, àti láti jọ̀wọ́ àwọn tí a pa lára lọ́wọ́
ẹ̀kọ́
ìgbèkùn
ìwà
2 Timotiu 2:25 — Ẹni tí yóò máa kọ́ àwọn alátakò pẹ̀lú ìwà tútù, ní ìrètí pé Ọlọ́run lè fún wọn ní ________ sí ìmọ̀ òtítọ́
ìrònúpìwàdà
òmùgọ̀
sùúrù
Isaiah 28:9 — “Ta ni ẹni náà tí ó ń gbìyànjú àti kọ́? Ta ni ó sì ń ṣàlàyé ________ in rẹ̀ fún? Sí àwọn ọmọdé tí a já lẹ́nu ọmú wọn, sí àwọn tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà lẹ́nu ọmú.
ìròyìn
olùṣọ́-àgùntàn
ẹkún
Isaiah 28:10 — Nítorí tí í ṣe: báyìí ni orí, ṣe, kí o si túnṣe, ṣe kí o si túnṣe, àṣẹ n gorí àṣẹ, àṣẹ n gorí àṣẹ; díẹ̀ ________, díẹ̀ lọ́hùn.”
ọ̀dọ́-àgùntàn
níhìn-ín
ọ̀rá
1 Kọrinti 3:2 — Wàrà ni mo ti fi bọ́ yín, kì í ṣe ________; nítorí ẹ kò í tí le gbà á nísinsin yìí náà, ẹ kò í tí le gbà a.
oúnjẹ
títí
ìfẹ́
Heberu 5:14 — Ṣùgbọ́n oúnjẹ líle wà fún àwọn tí ó dàgbà, àwọn ẹni nípa ìrírí, tí wọn ń lo ọgbọ́n wọn láti fi ________ sáàrín rere àti búburú.
ìyàtọ̀
ìdáríjì
àìṣòdodo
Isaiah 40:13 — Ta ni ó ti mọ ọkàn Olúwa, tàbí tí ó ti ________ ọ ṣọ́nà gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn rẹ̀?
alágbára
ayọ̀
tọ́
Romu 10:2 — Nítorí mo gba ẹ̀rí wọn jẹ́ wí pé, wọ́n ní ________ fún Ọlọ́run, ṣùgbọ́n kì í ṣe gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀.
ìtara
dárí
ẹ̀gbọ́n
2 Peteru 3:18 — Ṣùgbọ́n ẹ máa dàgbà nínú ________ àti nínú ìmọ̀ Olúwa àti Olùgbàlà wa Jesu Kristi. Ẹni tí ògo wà fún nísinsin yìí àti títí láé! Àmín.
asán
ìrètí
oore-ọ̀fẹ́
Òwe 2:5 — Nígbà náà ni ìwọ yóò ________ Olúwa, ìwọ yóò sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.
fàdákà
bẹ̀rù
wúrà
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
