Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Iṣóra? — Ṣíṣe É Ní Ìṣe · Àwọn Ìwé Mímọ́ KJV Pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.
Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.
Heberu 11:6 — Ṣùgbọ́n láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣe é ṣe láti wù ú; nítorí ẹni tí ó bá ń tọ Ọlọ́run wá kò lè ṣàì ________ pé ó ń bẹ, àti pé òun ní olùṣẹ̀san fún àwọn tí o fi ara balẹ̀ wá a.
súnmọ́
gbàgbọ́
oore-ọ̀fẹ́
Òwe 8:17 — Mo fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn mi, àwọn tí ó sì ________ mi rí mi.
kọ́
wá
dúró
Saamu 63:1 — Ọlọ́run, ìwọ ni Ọlọ́run mi, nígbà gbogbo ni mo ń ṣàfẹ́rí rẹ, òǹgbẹ rẹ ń gbẹ ọkàn mi, ara mi fà sí ọ, ní ilẹ̀ ________ àti ilẹ̀ tí ń ṣàárẹ̀ níbi tí kò sí omi.
ahoro
tuntun
gbígbẹ
Isaiah 26:9 — Ọkàn mi ń pòùngbẹẹ̀ rẹ ní ọ̀gànjọ́ òru; ní ________ ni ẹ̀mí mi ń ṣàfẹ́rí rẹ. Nígbà tí ìdájọ́ rẹ bá sọ̀kalẹ̀ sórí ayé àwọn ènìyàn yóò kọ́ ìṣòdodo.
òwúrọ̀
odi
àfonífojì
Saamu 78:34 — Nígbàkígbà tí Ọlọ́run bá pa wọ́n, wọn yóò wá a kiri; wọn yóò fi ________ yípadà sí i.
olùgbàlà
ìtara
ìtìsẹ̀
Deuteronomi 4:29 — Bí ẹ̀yin bá wá Olúwa Ọlọ́run yín láti bẹ̀ ẹ́, ẹ ó ri i, bí ẹ bá wá a, pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ________ a yín.
àyà
owó
ọkọ
Òwe 3:13 — ________ ni fún ẹni tí ó ní ìmọ̀, ẹni tí ó tún ní òye sí i
fìtílà
Ìbùkún
ọgbà
Òwe 8:19 — Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ; ohun tí mò ń mú wá ju àṣàyàn ________ lọ.
ṣinṣin
bẹ̀rù
fàdákà
Òwe 4:23 — Ju gbogbo nǹkan tókù lọ, pa ọkàn rẹ mọ́, nítorí òun ni ________ ìyè.
owó
bínú
orísun
Deuteronomi 6:5 — Fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo ________ rẹ àti gbogbo ọkàn rẹ, àti gbogbo agbára rẹ.
owó
àyà
ọkọ
Deuteronomi 6:17 — Ẹ rí i dájú pé ẹ̀ ń pa àwọn ________ Olúwa Ọlọ́run yín mọ́ àti àwọn àṣẹ àti àwọn ìlànà tí ó ti fún un yín.
òfin
àyà
ọ̀tá
Deuteronomi 11:13 — Nítorí náà, bí ẹ bá gbọ́rọ̀ sí àṣẹ tí mo fún un yín lónìí tọkàntọkàn: tí ẹ fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run yín, tí ẹ sì sìn ín, pẹ̀lú gbogbo ________ yín àti gbogbo ọkàn yín:
àyà
owó
ọkọ
Joṣua 22:5 — Ṣùgbọ́n ẹ ṣọ́ra gidigidi láti pa àṣẹ àti òfin tí Mose ìránṣẹ́ Olúwa fi fún yin mọ́. Láti fẹ́ràn Olúwa Ọlọ́run yín, láti rìn nínú gbogbo ọ̀nà rẹ̀, láti gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ̀, láti dìímú ________ àti láti sìn ín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti gbogbo àyà yín.”
àkọ́bí
ọ̀kọ̀
ṣinṣin
Saamu 119:4 — Ìwọ ti la ________ rẹ̀ sílẹ̀ kí a sì pa wọ́n mọ́ gidigidi.
ìlànà
àfonífojì
ọpẹ́
Saamu 119:2 — Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ń pa ________ rẹ̀ mọ́ tí wọn sì ń wá a pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn.
ẹ̀ṣẹ̀
ọ̀tá
òfin
Òwe 14:23 — Gbogbo iṣẹ́ àṣekára ló máa ń mú ________ wá, ṣùgbọ́n ẹjọ́ rírò lásán máa ń ta ni lósì ni.
èrè
ìmọ̀
ṣinṣin
Òwe 20:13 — Má ṣe fẹ́ràn oorun, àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò di tálákà. Ma ṣe ________ ìwọ yóò sì ní oúnjẹ láti tún fi tọrọ.
asán
fìtílà
sùn
2 Peteru 1:5 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ________, àti ìmọ̀ kún ìwà rere;
agbára
ẹ̀mí
ìgbàgbọ́
1 Kọrinti 15:58 — Nítorí náà ẹ̀yin ará mi olùfẹ́ ẹ máa dúró ṣinṣin, láìyẹsẹ̀, kí ẹ máa pọ̀ si í ní iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, ní ìwọ̀n bí ẹ̀yin ti mọ̀ pé iṣẹ́ yin kì í ṣe ________ nínú Olúwa.
ẹ̀rí
asán
ìwà
Galatia 6:9 — Ẹ má sì jẹ́ kí àárẹ̀ ọkàn mú wa ní ṣíṣe rere, nítorí tí a ó kórè nígbà tí ________ bá dé, bí a kò bá ṣe àárẹ̀.
ìwé
àkókò
ìgbà
1 Timotiu 6:12 — Máa ja ìjà rere ti ìgbàgbọ́, di ìyè àìnípẹ̀kun mú nínú èyí tí a pè ọ sí, ti ìwọ sì ṣe ìjẹ́wọ́ rere níwájú ________ púpọ̀.
aposteli
ẹlẹ́rìí
ìjìnlẹ̀
2 Timotiu 2:3 — Ṣe ________ pẹ̀lú mi nínú ìpọ́njú, bí ọmọ-ogun rere Jesu Kristi.
ọ̀ràn
alábápín
ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́
2 Timotiu 2:4 — Kò sí ẹni tí ń jagun ti ń fi ohun ayé yìí dí ara rẹ̀ lọ́wọ́, kí ó lè mú inú ẹni tí ó ________ ni ọmọ-ogun dùn.
yàn
ọlá
rán
Efesu 6:11 — Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin lè kọ ojú ìjà sí ________ èṣù.
ìrẹ̀lẹ̀
ìgboyà
àrékérekè
2 Kọrinti 7:11 — Kíyèsi i, nítorí ohun kan náà yìí tí a mú yin banújẹ́ fún bí ẹni ________, irú ìmúraṣíṣẹ́ tí ó mú jáde nínú yín, wíwẹ ara yín mọ́ ń kọ́, ìbànújẹ́ ń kọ́, ìpayà ń kọ́, ìfojúṣọ́nà ń kọ́, ìtara ń kọ́, ìjẹ́ni-níyà ń kọ́. Nínú ohun àmì kọ̀ọ̀kan yìí ni ẹ̀yin ti fi ara yín hàn bí aláìlẹ́bi nínú ọ̀ràn náà.
ìwà-bí-Ọlọ́run
ìgbọ́ràn
ìdánwò
2 Kọrinti 8:7 — Ṣùgbọ́n bí ẹ̀yin ti pọ̀ lóhùn gbogbo, ní ìgbàgbọ́, àti ọ̀rọ̀ àti ìmọ̀, àti nínú iṣẹ́ ìyìnrere gbogbo, àti ní ìfẹ́ yín sí wa, ẹ rí i wí pé ẹ̀yin pọ̀ sí i nínú ________ ọ̀fẹ́ yìí pẹ̀lú.
ayọ̀
ẹ̀bùn
ọpẹ́
2 Kọrinti 8:16 — Ṣùgbọ́n ọpẹ́ ní fún Ọlọ́run ẹni tí ó fi ìtara àníyàn kan náà yìí sí ọkàn ________ fún yín.
Titu
Romu
Efa
2 Kọrinti 8:22 — Àwa sì ti rán arákùnrin wa pẹ̀lú wọn, ẹni tí àwa rí dájú nígbà púpọ̀ pé ó ní ìtara nínú ohun púpọ̀, ṣùgbọ́n ní ________ yìí ni ìtara rẹ̀ túbọ̀ pọ̀ sí i nípa ìfọkàntán ńlá tí ó ní sí yín.
ìsinsin
nígbàkígbà
ẹ̀bùn
2 Timotiu 1:17 — Ṣùgbọ́n nígbà tí ó wà ni ________, ó fi ẹ̀sọ̀ wá mi, ó sì rí mi.
Romu
Timotiu
Efesu
Ọ̀nà Asopọ̀ Ti Dàkọ
Ẹ̀kọ́ yìí ha ti ràn ọ́ lọ́wọ́? Pín ẹ̀rí kúkúrú tàbí ẹ̀rí rẹ ní kíkún — ìtàn rẹ yóò ràn ẹnìkan mìíràn lọ́wọ́ láti rí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yìí.
Fi ìtẹ̀síwájú rẹ pamọ́
Àṣàyàn ni. O kì í nílò àkáǹtì láti lo ojú-òpó yìí.
Àwọn ère idanwo rẹ àti ìwé-ẹ̀rí rẹ yóò wà láìṣòfò bí o bá yí fóònù rẹ padà tàbí bá nu browser rẹ.
Padà bọ̀ sí ìlọsíwájú
Dídá ìtẹ̀síwájú padà yóò rọ́pò ìtẹ̀síwájú tó wà lórí ẹ̀rọ yìí, ìwé-ẹ̀rí èyíkéyìí tí o bá tẹ̀ jáde lẹ́yìn náà yóò sì gbé orúkọ tó wà nínú àkọsílẹ̀.



