🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ All languages
See More Jesus

Ta Ni Jésù? — Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì KJV Pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.

This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.

Isaiah 9:6 — Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, a fi ọmọkùnrin kan fún wa, ìjọba yóò sì wà ní èjìká rẹ̀. A ó sì máa pè é ní Ìyanu Olùdámọ̀ràn, Ọlọ́run ________, Baba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà.
ayọ̀
òdodo
Alágbára
Johanu 1:18 — Kò sí ẹni tí ó rí Ọlọ́run rí, bí kò ṣe òun ________, àní ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo, ẹni tí òun pàápàá jẹ́ Ọlọ́run, tí ó sì wà ní ìbáṣepọ̀ tí ó súnmọ́ jùlọ pẹ̀lú baba, òun náà ni ó sì fi í hàn.
ìfẹ́
ọlá
nìkan
Malaki 3:1 — “Wò ó, Èmi yóò ran ìránṣẹ́ mi, yóò tún ________ ṣe ṣáájú mi. Nígbà náà ni Olúwa, tí ẹ̀yin ń wa, yóò dé ni òjijì sí tẹmpili rẹ̀; àní oníṣẹ́ májẹ̀mú náà, tí inú yín dùn sí, yóò dé,” ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.
ọ̀nà
ẹnu
orí
Gẹnẹsisi 22:2 — Ọlọ́run sì wí pé, “Mú ọmọ rẹ, àní Isaaki ọmọ rẹ kan ṣoṣo nì, tí ìwọ ________, lọ sí ilẹ̀ Moria, kí o sì fi rú ẹbọ sísun níbẹ̀ lórí ọ̀kan nínú àwọn òkè tí èmi yóò sọ fún ọ.”
àpótí
fẹ́ràn
gbẹ́kẹ̀lé
Johanu 19:17 — Nítorí náà, wọ́n mú Jesu, ó sì jáde lọ, ó ru ________ fúnra rẹ̀ sí ibi tí à ń pè ní ibi agbárí, ní èdè Heberu tí à ń pè ní Gọlgọta.
àgbélébùú
ọ̀rẹ́
ọkọ
Johanu 1:29 — Ní ọjọ́ kejì, Johanu rí Jesu tí ó ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Wò ó, ________ Ọlọ́run, ẹni tí ó kó ẹ̀ṣẹ̀ ayé lọ!
nìkan
ayérayé
Ọ̀dọ́-àgùntàn
Isaiah 53:6 — Gbogbo wa bí ________, ti ṣìnà lọ, ẹnìkọ̀ọ̀kan wa ti yà sí ọ̀nà ara rẹ̀; Olúwa sì ti gbé e ka orí ara rẹ̀ gbogbo àìṣedéédéé wa.
àgùntàn
ọ̀pá
odi
Isaiah 53:7 — A jẹ ẹ́ ní yà, a sì pọ́n ọn lójú, síbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀; a mú un wá gẹ́gẹ́ bí ọ̀dọ́-àgùntàn sọ́dọ̀ alápatà, àti gẹ́gẹ́ bí àgùntàn tí ó ________ níwájú olùrẹ́run rẹ̀, síbẹ̀ kò ya ẹnu rẹ̀.
òtítọ́
ìparun
dákẹ́
Isaiah 7:14 — Nítorí náà, Olúwa fúnra ara rẹ̀ ni yóò fún ọ ní àmì kan. ________ kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Emmanueli.
Wúńdíá
àmùrè
ejò
Mika 5:2 — “Ṣùgbọ́n ìwọ, ________ Efrata, bí ìwọ ti jẹ́ kékeré láàrín àwọn ẹ̀yà Juda, nínú rẹ ni ẹni tí yóò jẹ́ olórí ní Israẹli yóò ti jáde tọ̀ mí wá, ìjáde lọ rẹ̀ sì jẹ́ láti ìgbà àtijọ́, láti ìgbà láéláé.”
Eufurate
Karmeli
Bẹtilẹhẹmu
Gẹnẹsisi 3:15 — Èmi yóò sì fi ọ̀tá sí àárín ìwọ àti obìnrin náà, àti sí àárín irú-ọmọ rẹ àti irú-ọmọ obìnrin náà; òun yóò fọ́ ________ rẹ, ìwọ yóò sì bù ú jẹ ní gìgísẹ̀.”
ẹnu
orí
ìránṣẹ́
Johanu 1:14 — Ọ̀rọ̀ náà sì di ara, òun sì ń bá wa gbé. Àwa sì ti rí ògo rẹ̀, àní ògo ọmọ rẹ kan ṣoṣo, tí ó ti ọ̀dọ̀ Baba wá, ó kún fún ________ àti òtítọ́.
oore-ọ̀fẹ́
nìkan
ọlá
Johanu 5:39 — Ẹ̀yin ń wá ________ mímọ́ nítorí ẹ̀yin rò pé nínú wọn ni ẹ̀yin ní ìyè tí kò nípẹ̀kun. Wọ̀nyí sì ni àwọn tí ó ń jẹ́rìí mi.
àkókò
ìwé
ẹ̀mí
Romu 3:23 — Gbogbo ènìyàn ni ó ṣá ti ṣẹ̀, tí wọ́n sì kùnà ________ Ọlọ́run
ògo
baba
ẹnu
Heberu 9:22 — Ó sì fẹ́rẹ̀ jẹ́ ohun gbogbo ni a fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀nù gẹ́gẹ́ bí òfin; àti pé láìsí ìtàjẹ̀ sílẹ̀ kò sí ________.
ìyàtọ̀
ìdáríjì
ìdíbàjẹ́
Heberu 1:8 — Ṣùgbọ́n ó sọ nípa tí Ọmọ rẹ̀ pé, “________ rẹ, Ọlọ́run, láé àti láéláé ni, ọ̀pá aládé òdodo ni ọ̀pá ìjọba rẹ.
ipò
àánú
Ìtẹ́
Saamu 110:1 — Olúwa sọ fún Olúwa mi pé, “Ìwọ jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi, títí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ________ rẹ.”
Olùdáǹdè
ìtara
ìtìsẹ̀
1 Kọrinti 15:20 — Ǹjẹ́ nísinsin yìí Kristi tí jíǹde kúrò nínú òkú, ó sì dí ________ nínú àwọn tí ó sùn.
àkọ́bí
èdìdì
kéré
Kolose 1:27 — Àwọn ẹni tí Ọlọ́run yàn láti fihàn láàrín àwọn aláìkọlà nípa ọ̀rọ̀ ògo ohun ìjìnlẹ̀ yìí, èyí tí í ṣe Kristi ________ ògo nínú yín.
oore-ọ̀fẹ́
ìrètí
nìkan
Ìfihàn 1:7 — “Kíyèsi i, o ń bọ̀ nínú ________, gbogbo ojú ni yóò sì rí i, àti àwọn tí ó gún un ní ọ̀kọ̀ pẹ̀lú”; àti gbogbo orílẹ̀-èdè ayé ni “yóò sì máa pohùnréré ẹkún nítorí rẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ náà ni! Àmín.
ìràwọ̀
èṣù
àwọsánmọ̀
Johanu 3:16 — “Nítorí Ọlọ́run fẹ́ aráyé tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́, tí ó fi ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo fún ni, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá gbà á gbọ́, má bà á ṣègbé, ṣùgbọ́n kí ó lè ní ìyè ________.
jókòó
èṣù
àìnípẹ̀kun

← Back to the study