Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọgbọ́n? — Apá 2 · Ẹsẹ Bíbélì KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
Òwe 1:7 — Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìbẹ̀rẹ̀ ìmọ̀, ṣùgbọ́n ________ kẹ́gàn ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́.
èso
aláìgbọ́n
ẹlẹ́ṣẹ̀
1 Ọba 3:9 — Nítorí náà fi ọkàn ìmòye fún ìránṣẹ́ rẹ láti le ṣàkóso àwọn ènìyàn rẹ àti láti mọ ________ láàrín rere àti búburú. Nítorí ta ni ó lè ṣe àkóso àwọn ènìyàn ńlá rẹ yìí?”
òmùgọ̀
ìyàtọ̀
òfúrufú
Òwe 2:6 — Nítorí Olúwa ni ó ń fún ni ní ọgbọ́n, láti ________ rẹ̀ sì ni ìmọ̀ àti òye ti ń wá.
ẹnu
ọkàn
agbára
1 Kọrinti 1:25 — Nítorí pé ________ Ọlọ́run jù ọgbọ́n ènìyàn lọ; àti aláìlera Ọlọ́run ni agbára jù ìlera ènìyàn lọ.
ìwà
òmùgọ̀
tútù
1 Kọrinti 3:19 — Nítorí ọgbọ́n ayé yìí jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run. Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ nínú Ìwé Mímọ́ pé, “Ẹni ti tí ó mu àwọn ọlọ́gbọ́n nínú ________ wọn”;
ìgboyà
àrékérekè
ìyàtọ̀
Jakọbu 3:17 — Ṣùgbọ́n ọgbọ́n tí ó ti òkè wá jẹ́ mímọ́ ní àkọ́kọ́, ti ________, àti ti ìrẹ̀lẹ̀, kì í sì í ṣòro láti bẹ̀, ó kún fún àánú àti fún èso rere, kì í ṣe ojúsàájú, a sì máa sọ òtítọ́.
fẹ́
ògo
àlàáfíà
1 Kọrinti 1:24 — Ṣùgbọ́n sí àwọn tí Ọlọ́run tí pè, àti àwọn Júù àti àwọn Giriki, Kristi ni ________ Ọlọ́run, àti ọgbọ́n Ọlọ́run.
dìde
dúró
agbára
Kolose 2:3 — Nínú ẹni tí a fi gbogbo ________ ìjìnlẹ̀ ọgbọ́n àti ìmọ̀ pamọ́ sí.
ètè
ìṣúra
apá
Òwe 3:13 — Ìbùkún ni fún ẹni tí ó ní ìmọ̀, ẹni tí ó tún ní ________ sí i
kórìíra
òye
ọrọ̀
Òwe 3:18 — Igi ìyè ni ó jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó bá gbà á; àwọn tí ó bá sì dìímú yóò rí ________ gbà.
ọgbà
ìbùkún
ẹ̀dá
Òwe 4:7 — Ọgbọ́n ni ó ga jù; nítorí náà gba ọgbọ́n. Bí ó tilẹ̀ ná gbogbo ohun tí o ní, gba ________.
ìmọ̀
kórìíra
òye
Jakọbu 3:13 — Ta ni ó gbọ́n tí ó sì ní ìmọ̀ nínú yín? Ẹ jẹ́ kí ó fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nípa ìwà rere, nípa ìwà ________ ti ọgbọ́n.
líle
tútù
sùúrù
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
