🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ All languages
See More Jesus

Kí Ni Bíbélì Wí Nípa Ìkóra-Ẹni-Níjàánu (Ìwọ̀ntúnwọ̀nsì)? — Apá Kejì · Àwọn Ìwé Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.

This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.

Galatia 5:22 — Ṣùgbọ́n èso ti Ẹ̀mí ni ìfẹ́, ayọ̀, àlàáfíà, ________, ìwà pẹ̀lẹ́, ìṣoore, ìgbàgbọ́
ìpamọ́ra
ìbọ̀rìṣà
àrólé
Galatia 5:23 — ìwà ________, àti ìkóra-ẹni níjanu, òfin kan kò lòdì sí irú wọ̀nyí
tútù
òmùgọ̀
àgbèrè
Òwe 16:32 — Ó sàn láti jẹ́ onísùúrù ju ajagun ènìyàn lọ, ẹni tí ó pa ìbínú mọ́ra ju ajagun ________ ìlú lọ.
ṣègbé
aláìní
ṣẹ́gun
1 Peteru 1:13 — Nítorí náà, ẹ múra ọkàn yín sílẹ̀, ẹ kó ara yín ní ìjánu, kí ẹ sì fi ìrètí yín ní kíkún sí oore-ọ̀fẹ́, èyí tí a ń mu bọ̀ fún yin ni ìgbà ________ Jesu Kristi.
ìfarahàn
olùfisùn
ìṣògo
1 Peteru 5:8 — Ẹ máa wà ni àìrékọjá, ẹ máa ṣọ́ra; nítorí èṣù ọ̀tá yín, bí i ________ tí ń ké ramúramù, ó ń rìn káàkiri, ó ń wa ẹni tí yóò pajẹ.
àgbélébùú
àyànfẹ́
kìnnìún
1 Tẹsalonika 5:8 — Ṣùgbọ́n àwa jẹ́ ti ìmọ́lẹ̀, ẹ jẹ́ kí a pa ara wa mọ́, ní gbígbé ìgbàgbọ́ wọ̀ àti ìfẹ́ bí ________ ni òru àti ìrètí ìgbàlà bí àṣíborí.
olè
ìgbàyà
ìgbìmọ̀
1 Kọrinti 6:12 — “Ohun gbogbo ní ó tọ́ fún mi,” ṣùgbọ́n kì í ṣe ohun gbogbo ni ó ní ________. “Ohun gbogbo ni ó yẹ fún mi,” ṣùgbọ́n èmi kì yóò jẹ́ kí ohunkóhun ṣe olórí fun mi.
asán
èrè
ìyìnrere
Romu 6:12 — Nítorí náà kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ jẹ ọba lórí ara ________ yín kí ó lè ba à máa ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀.
àìlera
kíkú
àyànfẹ́
Romu 6:13 — Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀yà ara yín kan di ohun èlò ohun búburú, nípa ẹ̀ṣẹ̀ dídá. Ṣùgbọ́n ẹ fi wọn fún Ọlọ́run pátápátá. Wọ́n ti di ààyè, ẹ jẹ́ kí wọn di ohun èlò ní ọwọ́ Ọlọ́run, kí ó lè lò wọ́n fún àwọn ________ rẹ̀ tí ó dára.
ìlànà
èso
ìpọ́njú
Romu 13:14 — Ṣùgbọ́n ẹ gbé Jesu Kristi Olúwa wọ̀, kí ẹ má sì pèsè fún ara, láti máa mú ________ rẹ̀ ṣẹ.
ẹlẹ́ṣẹ̀
ìlérí
ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́
Daniẹli 1:8 — Ṣùgbọ́n Daniẹli pinnu ní ọkàn ara rẹ̀ pé òun kò ní ba ara òun jẹ́ pẹ̀lú oúnjẹ àti wáìnì ọba, nígbà náà ni ó gba ààyè lọ́wọ́ olórí àwọn ________ wí pé òun kò fẹ́ ba ara òun jẹ́ ní ọ̀nà yìí.
kìnnìún
ewé
ìwẹ̀fà
1 Kọrinti 9:25 — Gbogbo ẹni tí ó ń sáré ìje a máa lọ nínú ìsẹ́ra-ẹni tí ó lágbára. Wọ́n ń ṣe èyí láti gba adé ________. Ṣùgbọ́n àwa ń sá eré ìje tiwa láti fi gba adé ọ̀run àìdíbàjẹ́ láéláé.
ìdíbàjẹ́
ìyàtọ̀
ìfihàn
Gẹnẹsisi 39:12 — Ó sì di aṣọ Josẹfu mú, ó sì wí pé, “Wá bá mi ________!” Ṣùgbọ́n Josẹfu fi aṣọ rẹ̀ sílẹ̀ sí i lọ́wọ́, ó sì sá jáde.
lòpọ̀
nìyí
pamọ́
2 Peteru 1:6 — àti àìrékọjá kún ________; àti sùúrù kún àìrékọjá; àti ìwà-bí-Ọlọ́run kún sùúrù.
oore-ọ̀fẹ́
mọ̀
ìmọ̀
Titu 2:12 — Ó ń kọ́ wa láti sẹ́ ________ àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ayé, kí a sì máa wà ní àìrékọjá, ní òdodo àti ní ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsinsin yìí
ìyapa
àìwà-bí-Ọlọ́run
ìsọdọmọ
Titu 2:13 — bí a ti ń wọ́nà fún ìrètí tó ní bùkún, èyí ń ní ìfarahàn ________ Ọlọ́run wa tí ó tóbi àti Olùgbàlà wa Jesu Kristi.
èrè
àlàáfíà
ògo

← Back to the study