Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìṣọ́ra? — Ìpìlẹ̀ · Ìwé Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.
Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.
2 Peteru 1:5 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
oore-ọ̀fẹ́
asán
ìmọ̀
Òwe 12:24 — Ọwọ́ àìṣọ̀lẹ yóò jẹ ọba ṣùgbọ́n ọ̀lẹ ṣíṣe a máa yọrí sí ________ ṣíṣe.
ejò
èrè
ẹrú
Òwe 15:19 — Ọ̀nà ọ̀lẹ ni ẹ̀gún dí, ṣùgbọ́n ọ̀nà ________ já geerege ni.
olódodo
kórìíra
oúnjẹ
Òwe 19:24 — Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú àwo oúnjẹ; kò tilẹ̀ ní mú u padà wá sí ________ rẹ̀.
ẹnu
ọ̀nà
baba
Òwe 21:25 — Ẹlẹ́rìí èké yóò ________, àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ yóò parun láé; nítorí tí ọwọ́ rẹ̀ kọ iṣẹ́ ṣíṣe.
ṣègbé
aláìní
kọ́
Òwe 24:30 — Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà ________ ènìyàn;
kìnnìún
aláìgbọ́n
ẹlẹ́ṣẹ̀
Oniwaasu 10:18 — Bí ènìyàn bá ń lọ́ra, àjà ilé a máa jì bí ọwọ́ rẹ̀ bá ń ṣe ________, ilé a máa jó.
Olùtùnú
ẹlẹ́ṣẹ̀
ọ̀lẹ
Òwe 19:15 — Ọ̀lẹ ṣíṣe máa ń fa oorun sísùn fọnfọn, ________ yóò sì máa pa ènìyàn tí ó lọ́ra.
ẹlẹ́ṣẹ̀
fìtílà
ebi
Òwe 6:6 — Tọ èèrà lọ, ìwọ ________; kíyèsi ìṣe rẹ̀, kí o sì gbọ́n!
ọlá
ọ̀lẹ
mọ̀
Òwe 26:13 — ________ wí pé, “Kìnnìún wà lójú ọ̀nà kìnnìún búburú ń ké ní ojú ọ̀nà.”
ẹ̀kọ́
Ọ̀lẹ
ègún
Òwe 21:5 — ________ àwọn olóye jásí èrè bí ìkánjú ṣe máa ń fa òsì kíákíá.
ọ̀rẹ́
Ètè
etí
Heberu 11:6 — Ṣùgbọ́n láìsí ìgbàgbọ́ kò ṣe é ṣe láti wù ú; nítorí ẹni tí ó bá ń tọ Ọlọ́run wá kò lè ṣàì ________ pé ó ń bẹ, àti pé òun ní olùṣẹ̀san fún àwọn tí o fi ara balẹ̀ wá a.
súnmọ́
gbàgbọ́
alààyè
Ìṣe àwọn Aposteli 18:24 — Júù kan sì wà tí a ń pè ni ________, tí a bí ni Alekisandiria, ó wá sí Efesu. Ó ní ẹ̀bùn ọ̀rọ̀ sísọ, ó sì mọ ìwé mímọ́ púpọ̀.
Galatia
Apollo
Akaia
2 Peteru 3:14 — Nítorí náà, olùfẹ́, bí ẹ̀yin ti ń retí irú nǹkan wọ̀nyí, ẹ múra gírí, kí a lè bá yín ní ________ ní àìlábàwọ́n, àti ní àìlábùkù lójú rẹ̀.
àlàáfíà
agbára
ẹ̀mí
2 Peteru 3:10 — Ṣùgbọ́n ọjọ́ Olúwa ń bọ̀ wá bí olè ní òru; nínú èyí tí àwọn ọ̀run yóò kọjá lọ pẹ̀lú ariwo ńlá, àti àwọn ìmọ́lẹ̀ ojú ọ̀run yóò sì ti inú ooru ________ gidigidi di yíyọ́, ayé àti àwọn iṣẹ́ tí ó wà nínú rẹ̀ yóò sì jóná túútúú.
gbígbóná
òkùnkùn
ìwà-bí-Ọlọ́run
Heberu 6:11 — Àwa sì fẹ́ kí olúkúlùkù yín máa fi irú àìsimi kan náà hàn, fún ________ ìdánilójú ìrètí títí dé òpin.
ìdáríjì
ìyàtọ̀
ẹ̀kún
Heberu 12:15 — Ẹ máa kíyèsára kí ẹnikẹ́ni má ṣe kùnà Oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run; kí gbòǹgbò ìkorò kan máa ba hù sókè kí ó sì yọ yín lẹ́nu, ọ̀pọ̀lọpọ̀ a sì ti ipa rẹ̀ di ________.
òkùnkùn
àìmọ́
àgbèrè
2 Peteru 1:10 — Nítorí náà, ará ẹ túbọ̀ máa ṣe àìsimi láti sọ ìpè àti yíyàn yín di dájúdájú, nítorí bí ẹ̀yin bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, ẹ̀yin kì yóò ________.
ikú
ṣubú
ṣègbé
2 Peteru 1:3 — Bí agbára rẹ̀ bí Ọlọ́run ti fún wa ní ohun gbogbo tí a nílò fún ṣe ti ìyè àti ti ________, nípa ìmọ̀ ẹni tí ó pè wá nípa Ògo àti ìṣeun rẹ̀.
sùúrù
ìwà-bí-Ọlọ́run
àìṣòdodo
1 Peteru 2:9 — Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ni ìran tí a yàn olú ________, Orílẹ̀-èdè mímọ́, ènìyàn ọ̀tọ̀ ki ẹ̀yin lè fi ọláńlá ẹni tí ó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn sínú ìmọ́lẹ̀ ìyanu rẹ̀ hàn.
ìwé
àlùfáà
ẹlẹ́ṣẹ̀
Filipi 4:8 — Ní àkótán, ará, ohunkóhun tí í ṣe òtítọ́, ohunkóhun tí í ṣe ọ̀wọ̀, ohunkóhun tí í ṣe títọ́ ohunkóhun tí í ṣe mímọ́, ohunkóhun tí í ṣe fífẹ́, ohunkóhun tí ó ni ________ rere, bí ìwà títọ́ kan bá wà, bí ìyìn kan bá sì wà, ẹ máa gba nǹkan wọ̀nyí rò.
ìròyìn
gbòǹgbò
panṣágà
Filipi 4:6 — Ẹ má ṣe ṣe àníyàn ohunkóhun; ṣùgbọ́n nínú ohun gbogbo, nípa àdúrà àti ________ pẹ̀lú ìdúpẹ́, ẹ máa fi ìbéèrè yín hàn fún Ọlọ́run.
ẹ̀bẹ̀
pípé
ìtùnú
Romu 12:1 — Nítorí náà mo fi ìyọ́nú Ọlọ́run bẹ̀ yín ará, kí ẹ̀yin kí ó fi ara yín fún Ọlọ́run ní ẹbọ ààyè mímọ́, ________, èyí ni iṣẹ́ ìsìn yín tí ó tọ̀nà.
ìtẹ́wọ́gbà
èrè
ìyanu
Romu 8:6 — Nítorí èrò ti ara ________ ni; ṣùgbọ́n èrò ti ẹ̀mí ni ìyè àti àlàáfíà.
kọ́
ikú
ṣubú
Isaiah 26:3 — Ìwọ yóò pa á mọ́ ní àlàáfíà ________ ọkàn ẹni tí ó dúró ṣinṣin, nítorí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ.
gbẹ̀san
títóbi
pípé
Efesu 4:23 — kí ẹ sì di ________ ni ẹ̀mí inú yín;
òtítọ́
tuntun
tẹmpili
1 Peteru 1:13 — Nítorí náà, ẹ múra ________ yín sílẹ̀, ẹ kó ara yín ní ìjánu, kí ẹ sì fi ìrètí yín ní kíkún sí oore-ọ̀fẹ́, èyí tí a ń mu bọ̀ fún yin ni ìgbà ìfarahàn Jesu Kristi.
ẹ̀ṣẹ̀
ọkàn
ọkọ
Ọ̀nà Asopọ̀ Ti Dàkọ
Ẹ̀kọ́ yìí ha ti ràn ọ́ lọ́wọ́? Pín ẹ̀rí kúkúrú tàbí ẹ̀rí rẹ ní kíkún — ìtàn rẹ yóò ràn ẹnìkan mìíràn lọ́wọ́ láti rí ojúlé wẹ́ẹ̀bù yìí.
Fi ìtẹ̀síwájú rẹ pamọ́
Àṣàyàn ni. O kì í nílò àkáǹtì láti lo ojú-òpó yìí.
Àwọn ère idanwo rẹ àti ìwé-ẹ̀rí rẹ yóò wà láìṣòfò bí o bá yí fóònù rẹ padà tàbí bá nu browser rẹ.
Padà bọ̀ sí ìlọsíwájú
Dídá ìtẹ̀síwájú padà yóò rọ́pò ìtẹ̀síwájú tó wà lórí ẹ̀rọ yìí, ìwé-ẹ̀rí èyíkéyìí tí o bá tẹ̀ jáde lẹ́yìn náà yóò sì gbé orúkọ tó wà nínú àkọsílẹ̀.



