🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ All languages
See More Jesus

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Rere Àti Búburú? — Ìpìlẹ̀ · Ìwé Mímọ́ KJV Pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.

This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.

Heberu 5:14 — Ṣùgbọ́n oúnjẹ líle wà fún àwọn tí ó dàgbà, àwọn ẹni nípa ìrírí, tí wọn ń lo ọgbọ́n wọn láti fi ________ sáàrín rere àti búburú.
ìyàtọ̀
ìdáríjì
àìṣòdodo
Deuteronomi 30:15 — Wò ó mo gbé kalẹ̀ síwájú u yín lónìí, ìyè àti àlàáfíà, ikú àti ________.
òkùnkùn
ìparun
àìmọ́
Òwe 1:24 — Ṣùgbọ́n ________ bí ẹ ti kọ ìpè ní ìgbà tí mo pè kò sì sí ẹni tí ó kọ ibi ara sí mi gbà tí mo na ọwọ́ sí wọn
níwọ̀n
mọ̀
ọ̀lẹ
Òwe 1:29 — Níwọ́n bí wọ́n ti ________ ìmọ̀ tí wọ́n sì kọ̀ láti bẹ̀rù Olúwa.
kórìíra
pín
kọ́
Jeremiah 13:23 — Ǹjẹ́ Etiopia le yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Tàbí ________ lè yí àwọ̀ rẹ̀ padà? Bí èyí kò ti lè rí bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin tí ìwà búburú bá ti mọ́ lára kò lè ṣe rere.
ìkunra
ẹkùn
ìparun
Òwe 4:14 — Má ṣe gbé ẹsẹ̀ rẹ sí ojú ọnà àwọn ènìyàn ________ tàbí kí o rìn ní ọ̀nà àwọn ẹni ibi.
kórìíra
búburú
ìdájọ́
Òwe 4:18 — Ipa ọ̀nà ________ dàbí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ oòrùn tí ń tànmọ́lẹ̀ sí i títí ọjọ́ fi kanrí
kórìíra
olódodo
ìmọ̀
Gẹnẹsisi 2:8 — Olúwa Ọlọ́run sì gbin ọgbà kan sí ________ ní ìhà ìlà-oòrùn, níbẹ̀ ni ó fi ọkùnrin náà tí ó ti dá sí.
Edeni
Hamu
Midiani
Gẹnẹsisi 2:15 — Olúwa Ọlọ́run mú ọkùnrin náà sínú ọgbà ________ láti máa ṣe iṣẹ́ níbẹ̀, kí ó sì máa ṣe ìtọ́jú rẹ̀.
Hamu
Gerari
Edeni
Gẹnẹsisi 2:16 — Olúwa Ọlọ́run sì ________ fún ọkùnrin náà pé, “Ìwọ lè jẹ lára èyíkéyìí èso àwọn igi inú ọgbà;
rìn
kún
pàṣẹ
Gẹnẹsisi 3:1 — Ejò sá à ṣe ________ ju àwọn ẹranko igbó yòókù tí Olúwa Ọlọ́run dá lọ. Ó sọ fún obìnrin náà pé, “Ǹjẹ́ òtítọ́ ha ni Ọlọ́run wí pé, ‘Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ jẹ èso èyíkéyìí lára àwọn igi tí ó wà nínú ọgbà’?”
ìkunra
alárékérekè
eékún
Gẹnẹsisi 3:6 — Nígbà tí obìnrin náà rí i wí pé èso igi náà dára fún oúnjẹ àti pé, ó sì dùn ún wò, àti pé ó ń mú ni ní ọgbọ́n, ó mú díẹ̀ níbẹ̀, ó sì jẹ ẹ́. Ó sì mú díẹ̀ fún ________ rẹ̀, ẹni tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.
ipò
ọ̀pá
ọkọ
Gẹnẹsisi 3:8 — Nígbà náà ni ọkùnrin náà àti ________ rẹ̀ gbọ́ ìró Olúwa Ọlọ́run bí ó ti ń rìn nínú ọgbà, nígbà tí ojú ọjọ́ tura, wọ́n sì fi ara pamọ́ kúrò níwájú Olúwa Ọlọ́run sí àárín àwọn igi inú ọgbà.
arákùnrin
aya
ọmọbìnrin
Saamu 56:3 — Nígbà tí ẹ̀rù bà ń bà mí, èmi o ________ ọ.
rántí
kọ̀
gbẹ́kẹ̀lé
Saamu 56:11 — nínú Ọlọ́run ni ________ mi: ẹ̀rù kì yóò bà mí. Kí ni ènìyàn lè ṣe sí mi?
ìgbẹ́kẹ̀lé
títóbi
ìparun
Gẹnẹsisi 3:22 — Olúwa Ọlọ́run sì wí pé, “Ọkùnrin náà ti dàbí ọ̀kan lára wa, ó mọ rere àti búburú. A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ó na ọwọ́ rẹ̀ kí ó mú lára èso igi ìyè kí ó sì jẹ, kí ó sì wà ________ títí láéláé.”
oúnjẹ
láààyè
sọkún
Gẹnẹsisi 6:5 — Olúwa sì rí bí ________ búburú ènìyàn ti ń gbilẹ̀ si, àti pé gbogbo èrò inú rẹ̀ kìkì ibi ni, ní ìgbà gbogbo.
àṣẹ
ìwà
òdodo
Gẹnẹsisi 8:20 — ________ sì mọ pẹpẹ fún Olúwa, ó sì mú lára àwọn ẹran tí ó mọ́ àti ẹyẹ tí ó mọ́, ó sì fi rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ.
Ṣela
Efa
Noa
Òwe 1:33 — ṣùgbọ́n ________ tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwu yóò sì wà nínú ìdẹ̀ra, láìsí ìbẹ̀rù ìpalára.”
san
ẹnìkan
mọ̀

← Back to the study