🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ All languages
See More Jesus

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Rere Àti Búburú? — Apá Kejì · Àwọn Ìwé Mímọ́ KJV Pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.

This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.

Heberu 5:14 — Ṣùgbọ́n oúnjẹ líle wà fún àwọn tí ó dàgbà, àwọn ẹni nípa ìrírí, tí wọn ń lo ọgbọ́n wọn láti fi ________ sáàrín rere àti búburú.
ìyàtọ̀
ìdáríjì
àìgbọ́ràn
2 Kọrinti 11:3 — Ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà mí, kí ó má bà á jẹ́ pé, bí ejò ti tan ________ jẹ́ nípasẹ̀ àrékérekè rẹ̀, a lè mú ọkàn yín ṣáko lọ kúrò nínú òtítọ́ yín àti ìfarajì fún Kristi.
Efa
Gomorra
Filipi
Romu 6:23 — Nítorí ikú ni èrè ẹ̀ṣẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè ________ nínú Kristi Jesu Olúwa wa.
ẹlẹ́ṣẹ̀
panṣágà
àìnípẹ̀kun
1 Johanu 2:16 — Nítorí ohun gbogbo tí ń bẹ nínú ayé: ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara, ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ojú, àti ________ ti ohun ti ó ní àti ohun tí ó ṣe kò wá láti ọ̀dọ̀ Baba bí kò ṣe láti ọwọ́ ayé.
ìlérí
èrè
ìgbéraga
Gẹnẹsisi 3:22 — Olúwa Ọlọ́run sì wí pé, “Ọkùnrin náà ti dàbí ọ̀kan lára wa, ó mọ rere àti búburú. A kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ó na ọwọ́ rẹ̀ kí ó mú lára èso igi ________ kí ó sì jẹ, kí ó sì wà láààyè títí láéláé.”
ìyè
èrè
gbin
Marku 7:21 — Nítorí pé láti inú ọkàn ènìyàn ni àwọn èrò búburú wọ̀nyí ti ń jáde wá: àgbèrè, olè, ìpànìyàn, ________
àyànfẹ́
panṣágà
fìtílà
Jeremiah 4:22 — “Aṣiwèrè ni àwọn ènìyàn mi; wọn kò mọ̀ mí. Wọ́n jẹ́ ________ ọmọ; wọ́n sì jẹ́ aláìlóye. Wọ́n mọ ibi ni ṣíṣe; wọn kò mọ bí a ti í ṣe rere.”
aláìgbọ́n
ewé
asà
Jeremiah 17:9 — Ọkàn ènìyàn kún fún ________ ju ohun gbogbo lọ, ó kọjá ohun tí a lè wòsàn. Ta ni èyí lè yé?
ẹ̀tàn
pọ́n
ọlọ́lá
Isaiah 7:15 — Òun yóò jẹ ________ àti oyin nígbà tí ó bá ní ìmọ̀ tó láti kọ ẹ̀bi àti láti yan rere.
wúwo
borí
wàrà
Saamu 97:10 — Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa, ________ ibi, ó pa ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́ ó gbà wọ́n ní ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú.
òkú
ṣubú
kórìíra
Òwe 3:7 — Má ṣe jẹ́ ________ lójú ara à rẹ bẹ̀rù Olúwa kí o sì kórìíra ibi.
ẹlẹ́ṣẹ̀
ọlọ́gbọ́n
pàṣán
Saamu 37:27 — Lọ kúrò nínú ibi, kí o sì máa ṣe rere; nígbà náà ni ìwọ yóò gbé ní ilẹ̀ náà títí ________.
ìdájọ́
láéláé
kọjá
1 Ọba 3:9 — Nítorí náà fi ọkàn ìmòye fún ìránṣẹ́ rẹ láti le ṣàkóso àwọn ènìyàn rẹ àti láti mọ ________ láàrín rere àti búburú. Nítorí ta ni ó lè ṣe àkóso àwọn ènìyàn ńlá rẹ yìí?”
òmùgọ̀
ìyàtọ̀
òfúrufú
1 Tẹsalonika 5:21 — Ṣùgbọ́n ẹ ________ gbogbo nǹkan wò. Ẹ di èyí tí ṣe òtítọ́ mú.
béèrè
dán
ìdí
Romu 16:19 — Nítorí ________ yín tànkálẹ̀ dé ibi gbogbo, nítorí náà mo ní ayọ̀ lórí yín; ṣùgbọ́n èmi fẹ́ kí ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n sí ohun tí ó ṣe rere, kí ẹ sì ṣe òpè sí ohun tí í ṣe búburú.
ìyàtọ̀
àìṣòdodo
ìgbọ́ràn
Ìṣe àwọn Aposteli 10:38 — Àní Jesu ti ________, gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti da Ẹ̀mí Mímọ́ àti agbára le lórí; ẹni tí ó ń kiri ṣe oore, ó ń ṣe ìmúláradá gbogbo àwọn tí èṣù sì ń pọ́n lójú; nítorí Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀.
Nasareti
Damasku
Sinai
1 Peteru 3:11 — Kí ó yà kúrò nínú ibi, kí ó sì máa ṣe rere; kí ó máa wá àlàáfíà, kí ó sì máa ________ rẹ̀.
àgbélébùú
lépa
láradá
Saamu 34:14 — Yà kúrò nínú ibi kí o sì ṣe rere; wá àlàáfíà, kí o sì ________ rẹ̀.
lépa
búra
èso
Gẹnẹsisi 3:13 — Nígbà náà ni Olúwa Ọlọ́run wí pé, “Èwo ni èyí tí ìwọ ṣe yìí?” Obìnrin náà dáhùn pé, “________ ni ó tàn mí jẹ, mo sì jẹ ẹ́.”
Ejò
Bóyá
wàrà
Romu 5:19 — Nítorí gẹ́gẹ́ bí nípa ________ ọkùnrin kan, ènìyàn púpọ̀ di ẹlẹ́ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni nípa ìgbọ́ràn ẹnìkan, a ó sọ ènìyàn púpọ̀ di olódodo.
ìfihàn
àìgbọ́ràn
ìyàtọ̀
Ìfihàn 2:7 — Ẹni tí ó bá ní etí kí ó gbọ́ ohun tí Ẹ̀mí ń sọ fún àwọn ________. Ẹni tí ó bá ṣẹ́gun ni èmi yóò fi èso igi ìyè nì fún jẹ, tí ń bẹ láàrín Paradise Ọlọ́run.
òkú
obìnrin
ìjọ

← Back to the study