🌐 Language
'Olelo Hawai'iAfaan Oromoobahasa IndonesiaBelarusianBrezhonegCebuanoChamorroChichewachiShonaChongthuCiyawoDanskDeutschEestiEnglishEspañolEsperantoeʋegbeFrançaisHausaHrvatskiIgboIlocanoItalianoKikuyuKiswahiliKiyombiKreyòl AyisyenLatinaLatviešulietuviųLingálaLugandaMagyarMahasuiMāoriNederlandsNorskPohnpeianPolskiPortuguêsQach’abelRomaniRomânăSanskritSetswanaShqipsrpski jezikSuomiSvenskaTagalogTiếng ViệtTonganTwiTürkçeUyghur tiliYorùbáÍslenskaČeštinaБългарскиРусскийУкраїнськаעבריתاردوالعربيةفارسیكوردی سۆرانیअहिराणी‎नेपालीभद्रवाही‎मराठीमानक हिन्दी‎हरियाणवी‎অসমীয়াবাংলাਪੰਜਾਬੀગુજરાતીଓଡ଼ିଆ‎தமிழ்తెలుగుಕನ್ನಡമലയാളംไทยဗမာἙλληνική中文日本語한국어+ Gbogbo Èdè
See More Jesus
Yorùbá

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Sùúrù? — Gbígbé E Yè · Ìwé Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

Ìdánwò Bíbélì

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Sùúrù? — Gbígbé E Yè · Ìwé Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì

Fún ìtọ́kasí kọ̀ọ̀kan nísàlẹ̀, yan ohun tí ẹsẹ náà kọ́ni. Ìwọ̀n rẹ yóò farahàn ní ìparí.

Èyí ni àdánwò tí a ń ṣàyẹ̀wò. Kọjá rẹ̀ láti jèrè ẹ̀san sí Ẹ̀rí-ìjẹ́rìí Ìfọwọ́sí Iṣẹ́-Ìsìn rẹ.

Romu 15:4 — Nítorí ohun gbogbo tí a kọ tẹ́lẹ̀, ni a kọ láti fi kọ́ wa pé, nípa sùúrù àti ________ ìwé mímọ́, kí àwa lè ní ìrètí.
ìfihàn
ìtùnú
ìyàtọ̀
Romu 15:5 — Kí Ọlọ́run, ẹni tí ń fún ni ní sùúrù àti ________ fún yin láti ní inú kan sí ara yín gẹ́gẹ́ bí i Jesu Kristi
ìtùnú
ìfihàn
ìyàtọ̀
Jakọbu 1:2 — Ẹ̀yin ará mi, nígbà tí ẹ̀yin bá bọ́ sínú onírúurú ________, ẹ ka gbogbo rẹ̀ sí ayọ̀;
ìdánwò
ìrẹ̀lẹ̀
tútù
Jakọbu 1:3 — nítorí tí ẹ̀yin mọ̀ pé, ìdánwò ________ yín ń ṣiṣẹ́ sùúrù.
ìgbàgbọ́
dúró
àlàáfíà
Jakọbu 1:4 — Ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí sùúrù kí ó ṣiṣẹ́ àṣepé, kí ẹ̀yin kí ó lè jẹ́ ________ àti aláìlábùkù tí kò ṣe aláìní ohunkóhun.
ìgboyà
pípé
àìlera
2 Peteru 1:5-6 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
ìmọ̀
asán
ọlá
Luku 8:15 — Ṣùgbọ́n ti ilẹ̀ rere ni àwọn tí wọ́n fi ọkàn òtítọ́ àti rere gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n dìímú ṣinṣin, wọ́n sì fi ________ so èso.
sùúrù
ìtùnú
dákẹ́
Isaiah 30:18 — Síbẹ̀síbẹ̀ Olúwa sì fẹ́ síjú àánú wò ọ́; ó dìde láti ṣàánú fún ọ. Nítorí Olúwa jẹ́ Ọlọ́run ìdájọ́. ________ ni fún gbogbo àwọn tí ó dúró dè é!
kedari
Ìbùkún
ọ̀sán
Isaiah 64:4 — Láti ìgbà àtijọ́ kò sí ẹni tí ó gbọ́ rí kò sí ________ kan tí ó gbọ́ ọ, kò sí ojú tí ó tí ì rí Ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn rẹ, tí ó máa ń ṣe nǹkan lórúkọ àwọn tí ó dúró dè é.
apá
òfin
etí
Saamu 40:1 — Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ dúró de Olúwa; ó sì ________ sí mi, ó sì gbọ́ ẹkún mi.
dẹtí
láìnídìí
oore-ọ̀fẹ́
Ẹkún Jeremiah 3:25 — Dídára ni Olúwa fún àwọn tí ó ní ________ nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.
títí
pamọ́
ìrètí
Ẹkún Jeremiah 3:26 — Ó dára kí a ní ________ fún ìgbàlà Olúwa.
ìwà
ìfẹ́
sùúrù
Ẹkún Jeremiah 3:27 — Ó dára fún ènìyàn láti gbé ________ nígbà tí ó wà ní èwe.
ọ̀rẹ́
ẹwà
àjàgà
Luku 21:19 — Nínú ìdúró ________ yín ni ẹ̀yin ó jèrè ọkàn yín.
baálẹ̀
panṣágà
ṣinṣin
Kolose 3:12 — Nítorí náà, bí àyànfẹ́ Ọlọ́run, ẹni mímọ́ àti olùfẹ́, ẹ gbé ọkàn ìyọ́nú wọ̀, ìṣoore, ìrẹ̀lẹ̀, inú ________ àti sùúrù.
àgbèrè
tútù
ètùtù
Efesu 4:1 — Nítorí náà, èmi òǹdè nínú Olúwa ń bẹ̀ yín pé kí ẹ̀yin máa gbé ìgbé ayé tí ó yẹ sí ________ tí a pè yín sí.
tẹríba
ìpè
ṣògo
Efesu 4:2 — Pẹ̀lú ________ gbogbo àti inú tútù, pẹ̀lú ìpamọ́ra, ẹ máa fi ìfẹ́ faradà fún ẹnìkejì yín.
ìtùnú
ìrẹ̀lẹ̀
ìdáríjì
Kolose 1:11 — pé kí a lè fi ipa gbogbo sọ yín di alágbára gẹ́gẹ́ bí agbára rẹ̀ àti ________ rẹ̀, kí ó lè ṣe é ṣe fún un yín láti máa tẹ̀síwájú nínú sùúrù àti ìpamọ́ra pẹ̀lú ayọ̀.
èrè
ògo
olóòtítọ́
Galatia 5:22 — Ṣùgbọ́n èso ti Ẹ̀mí ni ìfẹ́, ayọ̀, àlàáfíà, ìpamọ́ra, ìwà ________, ìṣoore, ìgbàgbọ́
pẹ̀lẹ́
ìyapa
wọ̀bìà
1 Tẹsalonika 5:14 — Ẹ̀yin ará mi, ẹ kìlọ̀ fún àwọn ọ̀lẹ ti ó wà ________ yín, ẹ gba àwọn tí ẹ̀rù ń bà ní ìyànjú, ẹ tọ́jú àwọn aláìlera pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, kí ẹ sì ní sùúrù pẹ̀lú gbogbo ènìyàn.
àlàáfíà
láàrín
ìfẹ́
Saamu 37:7 — Ìwọ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa, kí o sì fi ________ dúró dè é; má ṣe ṣe ìkanra nítorí àwọn tí ń rí rere ní ọ̀nà wọn, nítorí ọkùnrin náà ti mú èrò búburú ṣẹ.
òmùgọ̀
sùúrù
ẹ̀kún
Òwe 16:32 — Ó sàn láti jẹ́ onísùúrù ju ajagun ènìyàn lọ, ẹni tí ó pa ________ mọ́ra ju ajagun ṣẹ́gun ìlú lọ.
ẹsẹ̀
ìbínú
ìyá
Oniwaasu 7:8 — Òpin ọ̀rọ̀ dára ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ, ________ sì dára ju ìgbéraga lọ.
ìpọ́njú
ayọ̀
sùúrù
Jakọbu 5:8 — Ẹ̀yin pẹ̀lú, ẹ mú sùúrù; ẹ fi ________ yín balẹ̀, nítorí ìpadà wá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀.
ẹ̀ṣẹ̀
ọ̀nà
ọkàn
Heberu 12:1 — Nítorí náà bí a ti fi ìkùùkuu àwọsánmọ̀ tí o kún fún àwọn ẹlẹ́rìí tó báyìí yí wa ká, ẹ jẹ́ kí a pa ohun ìdíwọ́ gbogbo tì sí apá kan, àti ẹ̀ṣẹ̀ tí o rọrùn láti di mọ́ wa, kí a sì máa fi ________ súré ìje tí a gbé ka iwájú wa
ìwà
ìgbàlà
sùúrù
Heberu 12:2 — kí a máa wo Jesu Olùpilẹ̀ṣẹ̀ àti aláṣepé ìgbàgbọ́ wa; ẹni nítorí ________ tí a gbé ka iwájú rẹ, tí o faradà àgbélébùú láìka ìtìjú sí, tí ó sì jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún ìtẹ́ Ọlọ́run.
ìwà
ayọ̀
ìran
Heberu 12:3 — Máa ro ti ẹni tí ó faradà irú ìsọ̀rọ̀-òdì yìí láti ọ̀dọ̀ àwọn ________ si ara rẹ̀, kí ẹ má ba á rẹ̀wẹ̀sì ni ọkàn yín, kí àárẹ̀ si mu yín.
ẹlẹ́ṣẹ̀
ìlànà
èṣù
Heberu 10:36 — Nítorí ẹ̀yin kò le ṣe aláìní sùúrù, nítorí ìgbà tí ẹ̀yin bá ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run tan kí ẹ̀yin le ________ ìlérí náà.
ikú
gba
dìde
2 Timotiu 2:3 — Ṣe ________ pẹ̀lú mi nínú ìpọ́njú, bí ọmọ-ogun rere Jesu Kristi.
ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́
alábápín
ẹlẹ́ṣẹ̀

← Padà sí ẹ̀kọ́ náà