Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìwà Ìkóra-Ẹni-Níjàánu (Ìwọ̀ntúnwọ̀nsì)? — Ìpìlẹ̀ Náà · Àwọn Ẹsẹ Bíbélì KJV Pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
Galatia 5:22-23 — Ṣùgbọ́n èso ti Ẹ̀mí ni ìfẹ́, ayọ̀, àlàáfíà, ________, ìwà pẹ̀lẹ́, ìṣoore, ìgbàgbọ́
ìbọ̀rìṣà
àrólé
ìpamọ́ra
1 Ọba 21:1-4 — Ó sì ṣe lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí ________ ará Jesreeli sì ní ọgbà àjàrà kan ní Jesreeli, ní ẹ̀gbẹ́ ààfin Ahabu ọba Samaria.
Hiramu
Naboti
Ramoti
1 Ọba 21:7 — Jesebeli aya rẹ̀ sì wí pé, “Ṣé báyìí ni ìwọ yóò ṣe ṣe bí ọba lórí Israẹli? Dìde, jẹun! Kí o sì jẹ́ kí inú rẹ̀ dùn. Èmi yóò sì fún ọ ní ________ àjàrà Naboti ará Jesreeli.”
òfin
ọgbà
àjàgà
1 Ọba 21:20 — Ahabu sì wí fún Elijah pé, “Ìwọ ti rí mi, ìwọ ________ mi!” Ó sì dáhùn wí pé, “Èmi ti rí ọ, nítorí tí ìwọ ti tan ara rẹ láti ṣe búburú níwájú Olúwa.
ọ̀tá
ọmọbìnrin
orí
2 Peteru 2:15 — Wọ́n kọ ọ̀nà tí ó tọ́ sílẹ̀, wọ́n sì ṣáko lọ, wọ́n tẹ̀lé ọ̀nà Balaamu ọmọ Beori, ẹni tó fẹ́ràn èrè ________.
ìdánwò
àìṣòdodo
ìrònúpìwàdà
2 Samuẹli 11:2-4 — Ó sì ṣe, ní ìgbà ________ kan, Dafidi sì dìde ní ibùsùn rẹ̀, ó sì ń rìn lórí òrùlé ilé ọba, láti orí òrùlé náà ni ó sì rí obìnrin kan tí ó ń wẹ̀ ara rẹ̀; obìnrin náà sì ṣe arẹwà lójú láti wò.
àṣálẹ́
èrè
afọ́jú
Heberu 5:8 — Bí òun tilẹ̀ ń ṣe Ọmọ Ọlọ́run, síbẹ̀ ó kọ́ ________ nípa ohun tí ó jìyà rẹ̀.
àìṣòdodo
ìgbọ́ran
ìdáríjì
Filipi 2:8 — Ó sì wà ní ________ ènìyàn, ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, o sì tẹríba títí de ojú ikú, àní ikú lórí àgbélébùú.
àwòrán
èrè
àlàáfíà
1 Peteru 2:22-23 — “Òun kò dẹ́ṣẹ̀ kankan, bẹ́ẹ̀ sì ni, a kò rí ________ kan lẹ́nu rẹ̀.”
níwọ̀n
tẹríba
ẹ̀tàn
2 Peteru 1:5-6 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
ìmọ̀
mọ̀
oore-ọ̀fẹ́
1 Kọrinti 9:24-25 — Ẹ̀yin kò mọ̀ pé, olúkúlùkù ẹni tí ó ní ipa nínú eré ìje ni ó máa ń sáré, ṣùgbọ́n ẹnìkan ṣoṣo ni ń gba ipò ẹ̀bùn tí ó ga jù. Nítorí náà, ẹ sá eré ìje yín kí ẹ ba à le ________.
borí
ayọ̀
tọ́
Titu 2:11-12 — Nítorí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tó mú ________ wà ti fi ara hàn fún gbogbo ènìyàn.
ìgbàlà
ọgbọ́n
ìfẹ́
Heberu 12:16-17 — Kí o má bá à si àgbèrè kan tàbí aláìwà-bí-Ọlọ́run bi Esau, ẹni tí o tìtorí òkèlè oúnjẹ kan ta ogún ________ rẹ̀.
ìbí
òbí
ìṣògo
1 Johanu 2:16 — Nítorí ohun gbogbo tí ń bẹ nínú ayé: ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara, ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ojú, àti ________ ti ohun ti ó ní àti ohun tí ó ṣe kò wá láti ọ̀dọ̀ Baba bí kò ṣe láti ọwọ́ ayé.
sáré
ìlérí
ìgbéraga
Matiu 4:8-10 — Lẹ́ẹ̀kan sí i, ________ gbé e lọ sórí òkè gíga, ó sì fi gbogbo ilẹ̀ ọba ayé àti gbogbo ògo wọn hàn án.
èrè
dáhùn
èṣù
Romu 5:19 — Nítorí gẹ́gẹ́ bí nípa ________ ọkùnrin kan, ènìyàn púpọ̀ di ẹlẹ́ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni nípa ìgbọ́ràn ẹnìkan, a ó sọ ènìyàn púpọ̀ di olódodo.
ìfihàn
àìgbọ́ràn
àìṣòdodo
1 Kọrinti 10:13 — Kò sí ìdánwò kan tí ó ti bá yín, bí kò ṣe irú èyí tí ó mọ ________ fún ènìyàn, ṣùgbọ́n olódodo ni Ọlọ́run, ẹni ti kì yóò jẹ́ kí á dán an yín wò ju bí ẹ̀yin ti le gbà, ṣùgbọ́n tí yóò sì ṣe ọ̀nà àbáyọ pẹ̀lú nínú ìdánwò náà, kí ẹ̀yin ba à lè faradà á.
tẹríba
ebi
níwọ̀n
2 Peteru 1:6 — àti àìrékọjá kún ìmọ̀; àti sùúrù kún àìrékọjá; àti ________ kún sùúrù.
ìdánwò
ìgbọ́ràn
ìwà-bí-Ọlọ́run
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
