Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìwà-bí-Ọlọ́run? — Ìpìlẹ̀ · Àwọn Ìwé-Mímọ́ KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
2 Peteru 1:3 — Bí agbára rẹ̀ bí Ọlọ́run ti fún wa ní ohun gbogbo tí a nílò fún ṣe ti ìyè àti ti ________, nípa ìmọ̀ ẹni tí ó pè wá nípa Ògo àti ìṣeun rẹ̀.
sùúrù
ìwà-bí-Ọlọ́run
ìfẹ́
2 Peteru 1:4 — Nípa èyí tí ó fi àwọn ìlérí rẹ̀ tí ó tóbi púpọ̀ tí ó ṣe iyebíye fún wa: pé nípa ìwọ̀nyí ni kí ẹ̀yin lè di ________ nínú àbùdá ti Ọlọ́run, nígbà tí ẹ̀yin bá ti yọ kúrò nínú ìbàjẹ́ tí ó ń bẹ nínú ayé nípa ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́.
ìdánwò
ajá
alábápín
2 Peteru 1:5 — Àti nítorí ìdí èyí, ẹ máa ṣe àìsimi gbogbo, ẹ fi ìwà rere kún ìgbàgbọ́, àti ________ kún ìwà rere;
mọ̀
asán
ìmọ̀
2 Peteru 1:6 — àti àìrékọjá kún ________; àti sùúrù kún àìrékọjá; àti ìwà-bí-Ọlọ́run kún sùúrù.
mọ̀
asán
ìmọ̀
2 Peteru 1:7 — Àti ìfẹ́ ọmọnìkejì kún ________; àti ìfẹ́ni kún ìfẹ́ ọmọnìkejì.
sùúrù
ìwà-bí-Ọlọ́run
ìwà
Matiu 5:16 — Bákan náà, ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ̀ níwájú ènìyàn, kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín, kí wọn lè máa yin baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ________.
ìhòhò
bamitiisi
lógo
Romu 4:20 — Kò fi ________ ṣiyèméjì nípa ìlérí Ọlọ́run; ṣùgbọ́n ó lágbára sí i nínú ìgbàgbọ́ bí ó ti fi ògo fún Ọlọ́run
ìṣògo
àìgbàgbọ́
àyànfẹ́
Johanu 15:8 — Nínú èyí ní a yìn Baba mi ________ pé, kí ẹ̀yin kí ó máa so èso púpọ̀; ẹ̀yin ó sì jẹ́ ọmọ-ẹ̀yìn mi.
lógo
hàn
àgbélébùú
1 Kọrinti 6:20 — nítorí a ti rà yín ni ________ kan. Nítorí náà ẹ yìn Ọlọ́run lógo nínú ara yín, àti nínú ẹ̀mí yín, tì í ṣe ti Ọlọ́run.
òtítọ́
iye
ẹranko
2 Peteru 1:8 — Nítorí bí ẹ̀yin bá ní nǹkan wọ̀nyí tí wọ́n bá sì pọ̀, wọn kì yóò jẹ́ kí ẹ ṣe ọ̀lẹ tàbí ________ nínú ìmọ̀ Olúwa wa Jesu Kristi.
aláìléso
ìdíbàjẹ́
Sodomu
2 Peteru 1:9 — Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ṣe aláìní nǹkan wọ̀nyí, kò lè ríran ní òkèèrè, ó fọjú, ó sì ti ________ pé a ti wẹ òun nù kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ àtijọ́.
ṣẹ́gun
gbàgbé
ọlá
2 Peteru 1:10 — Nítorí náà, ará ẹ túbọ̀ máa ṣe àìsimi láti sọ ________ àti yíyàn yín di dájúdájú, nítorí bí ẹ̀yin bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, ẹ̀yin kì yóò ṣubú.
alẹ́
ìpè
sẹ́
2 Peteru 1:11 — Nítorí báyìí ni a ó pèsè fún yín lọ́pọ̀lọ́pọ̀ láti wọ ìjọba àìnípẹ̀kun ti Olúwa àti ________ wa Jesu Kristi.
Olùgbàlà
Heberu
Hiti
Romu 8:29 — Nítorí àwọn ẹni tí ó mọ̀ tẹ́lẹ̀, ni ó sì yàn tẹ́lẹ̀ láti rí bí ________ ọmọ rẹ̀, kí òun lè jẹ́ àkọ́bí láàrín àwọn arákùnrin púpọ̀.
ìtẹ́wọ́gbà
èrè
àwòrán
1 Peteru 2:9 — Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ni ìran tí a yàn olú àlùfáà, Orílẹ̀-èdè mímọ́, ènìyàn ọ̀tọ̀ ki ẹ̀yin lè fi ọláńlá ẹni tí ó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn sínú ìmọ́lẹ̀ ________ rẹ̀ hàn.
ìyanu
ọpẹ́
èso
Heberu 6:11-12 — Àwa sì fẹ́ kí olúkúlùkù yín máa fi irú àìsimi kan náà hàn, fún ẹ̀kún ìdánilójú ________ títí dé òpin.
oore-ọ̀fẹ́
alààyè
ìrètí
Luku 13:24 — “Ẹ làkàkà láti gba ojú ọ̀nà ________ wọlé, nítorí mo wí fún yín, ènìyàn púpọ̀ ni yóò wá ọ̀nà láti wọ̀ ọ́, wọn kì yóò sì lè wọlé.
ìkélé
tóóró
ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀
Ìfihàn 19:9 — Ó sì wí fún mi pé, “Kọ̀wé rẹ̀, ‘Ìbùkún ni fún àwọn tí a pè sí àsè alẹ́ ìgbéyàwó ________.’” Ó sì wí fún mi pé, “Ìwọ̀nyí ni ọ̀rọ̀ òtítọ́ Ọlọ́run.”
ọ̀dọ́-àgùntàn
ẹ̀mí
ìwé
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
