Ta Ni Jésù? — Apá 2 · Ẹsẹ Bíbélì KJV pẹ̀lú Àwọn Nọ́mbà Strong — Ìdánwò Bíbélì
For each reference below, choose what that verse teaches. Your score appears at the end.
This is the graded quiz. Pass it to earn credit toward your Ministry Certificate of Endorsement.
Sekariah 6:12 — Sì sọ fún un pé, ‘Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé, wo ọkùnrin náà ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹ̀ka; yóò sì yọ ẹ̀ka láti abẹ́ rẹ̀ wá, yóò si kọ́ ________ Olúwa wa.
Ejibiti
tẹmpili
Asiria
Gẹnẹsisi 14:18 — Melkisedeki ọba ________ sì mú oúnjẹ àti ọtí wáìnì jáde wá. Òun ni àlùfáà Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo.
Salẹmu
Jamini
Tola
Saamu 110:4 — Olúwa ti búra, kò sì í yí ọkàn padà pé, “Ìwọ ni àlùfáà, ní ipasẹ̀ ________.”
Melkisedeki
Abiramu
Rahabu
Heberu 7:1 — Nítorí Melkisedeki yìí, ọba ________, àlùfáà Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, ẹni tí ó pàdé Abrahamu bí ó ti ń padà bọ̀ láti ibi pípa àwọn ọba, tí ó sì súre fún un
Itali
Annasi
Salẹmu
Heberu 7:26 — Nítorí pé irú olórí àlùfáà bẹ́ẹ̀ ni o yẹ wá, mímọ́, àìlẹ́gàn, àìléèérí, tí a yà ________ kúrò láàrín àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbéga ju àwọn ọ̀run lọ.
sọ́tọ̀
parí
lógo
Matiu 26:26 — Bí wọ́n ti ń jẹun, Jesu sì mú ________ àkàrà kékeré kan, lẹ́yìn tí ó ti gbàdúrà sí i, ó bù ú, Ó fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, Ó wí pé, “Gbà, jẹ; nítorí èyí ni ara mi.”
ìwọ̀n
wàásù
sàn
Gẹnẹsisi 49:10 — Ọ̀pá oyè kì yóò kúrò ní Juda bẹ́ẹ̀ ni ọ̀pá-ìṣàkóso kì yóò kúrò láàrín ẹsẹ̀ rẹ̀, títí tí ________ tí ó ni í yóò fi dé, tí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóò máa wárí fún un.
Gerṣoni
Ṣilo
Kedari
2 Samuẹli 7:12 — Nígbà tí ọjọ́ rẹ bá pé, tí ìwọ ó sì ________ pẹ̀lú àwọn baba rẹ, èmi yóò sì gbé irú-ọmọ rẹ lékè lẹ́yìn rẹ, èyí tí ó ti inú rẹ jáde wá, èmi yóò sì fi ìdí ìjọba rẹ kalẹ̀.
ìpè
sùn
dàgbà
Saamu 132:11 — Olúwa ti búra nítòótọ́ fún Dafidi, Òun kì yóò yípadà kúrò nínú rẹ̀, nínú irú-ọmọ inú rẹ ni èmi ó gbé kalẹ̀ sí orí ________ rẹ.
ìtẹ́
májẹ̀mú
apá
Jeremiah 23:5 — “Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí, “tí Èmi yóò gbé ________ òdodo dìde fún Dafidi, ọba tí yóò lo ìjọba pẹ̀lú ọgbọ́n tí yóò sì ṣe òdodo àti ohun tí ó yẹ lórí ilẹ̀ náà.
ìròyìn
igbó
ẹ̀ka
Matiu 1:1 — Ìwé ________ Jesu Kristi, ẹni tí í ṣe ọmọ Dafidi, ọmọ Abrahamu:
ìfẹ́
ìran
ẹ̀ṣẹ̀
2 Timotiu 2:8 — Rántí Jesu Kristi, ti ó jíǹde kúrò nínú ________, láti inú irú-ọmọ Dafidi gẹ́gẹ́ bí ìyìnrere mi.
òkú
wúrà
ayọ̀
Ìfihàn 22:16 — “Èmi, Jesu, ni ó rán angẹli mi láti jẹ́rìí nǹkan wọ̀nyí fún yin ní tí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti irú-ọmọ Dafidi, àti ìràwọ̀ ________ tí ń tàn.”
àgùntàn
òwúrọ̀
ère
Matiu 3:16 — Bí ó si tí ṣe ìtẹ̀bọmi fún Jesu tán, Ó jáde láti inú omi. Ní àkókò náà ọ̀run ṣí sílẹ̀ fún un, Ó sì rí Ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀kalẹ̀ bí ________, ó sì bà lé e.
ìwúkàrà
àdàbà
nígbàkígbà
Johanu 1:32 — Nígbà náà ni Johanu jẹ́rìí sí i pé, “Mo rí Ẹ̀mí sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá bí ________, tí ó sì bà lé e.
àdàbà
ìkòkò
òwe
Matiu 28:18 — Nígbà náà ni Jesu wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Gbogbo ________ ni ọ̀run àti ní ayé ni a ti fi fún mi.
nìkan
bẹ̀rẹ̀
agbára
Johanu 14:26 — Ṣùgbọ́n ________ náà, Ẹ̀mí Mímọ́, ẹni tí Baba yóò rán ní orúkọ mi, òun ni yóò kọ́ yín ní ohun gbogbo, yóò sì rán yín létí ohun gbogbo tí mo ti sọ fún yín.
Olùtùnú
alẹ́
olùkọ́
2 Kọrinti 13:14 — ________ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.
ìyìnrere
ẹ̀bùn
Oore-ọ̀fẹ́
Efesu 4:4 — Ara kan ni ń bẹ, àti Ẹ̀mí kan, àní bí a ti pè yín sínú ________ kan nígbà tí a pè yín.
ìrètí
ìmọ̀
ìyìnrere
Heberu 8:1 — Nísinsin yìí, kókó ohun tí à ń sọ nìyí. Àwa ní irú olórí àlùfáà bẹ́ẹ̀, tí ó jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún ìtẹ́ ________ nínú àwọn ọ̀run
àgbélébùú
Ọláńlá
ìtìsẹ̀
Heberu 7:14 — Nítorí ó hàn gbangba pé láti inú ẹ̀yà ________ ni Olúwa wa ti dìde; nípa ẹ̀yà yìí Mose kò sọ ohunkóhun ní ti àwọn àlùfáà.
Juda
Noa
Salẹmu
Heberu 4:14 — Ǹjẹ́ bí a ti ní olórí àlùfáà ńlá kan, tí ó ti la àwọn ọ̀run kọjá lọ, Jesu Ọmọ Ọlọ́run, ẹ jẹ́ kí a di ________ wa mú ṣinṣin.
ìjẹ́wọ́
ìyànjú
ìdáríjì
Link copied
Has this study helped you? Share a short or your full testimony — your story helps someone else find this site.
Save your progress
Optional. You never need an account to use this site.
Keep your quiz scores and your certificate if you change phone or clear your browser.
Restore progress
Restoring replaces the progress on this device, and any certificate you print afterwards will carry the name on the record.
